Friday, July 18, 2025
HomeNews Busayo Adekunle - Drops "Faithful God" (Olorun J'olododo)

[Visual + Music] Busayo Adekunle – Drops “Faithful God” (Olorun J’olododo)

Nigerian gospel minister Busayo Adekunle’s heartfelt worship song, “Faithful God” (Olorun J’Olododo)

celebrating the steadfast faithfulness of God at every stage of life in Busayo Adekunle existence. This song, which is performed in a rich Yoruba blend, attests to God’s goodness.

He consistently fulfills his word and fulfills the promises he has made.

HIS Faithfulness is pure and true

“He cannot deny Himself, even if we are unfaithful” (2 Timothy 2:13)

This worship single is more than just a song, says Busayo Adekunle it is a statement of faith in God’s honesty, kindness, and covenant-keeping character, accompanied by anointed vocals, heartfelt lyrics, and a potent instrumental arrangement. Because God is always dependable, “Faithful God” encourages believers to cling to His promises, whether they are made in happy or difficult times.

Lyrics: of FAITHFUL GOD (OLORUN J’OLODODO)
By Busayo Adekunle


Chorus:
Lead: OLORUN Olododo ni o
Olu ninu orun, agba
oye sa lo je
Alatileyin asiwaju
ohun gbogbo
Alanu mi o se Oloore mi.

Stanza 1
Ka to da ye, sebi wo lo ti n joba
Ka to da awon oke nla nijoba RE ti wa atate
Koda ohun laseda ohun gbogbo Alanu mi
Ose Oloore mi.

Repeat: Ka to da ye, sebi wo lo ti wa
Kato da awon oke nla nijoba Re ti wa
Atete ko da ohun laseda ohun gbogbo
Alanu mi o se Oloore mi (OLORUN)!

Chorus….

Stanza 2:
Ododo Re, ko ma se sakawe
Olanla Re ko ma se fenu so, a fola sola
Afore danilola, Alanu mi o se Oloore mi.

Repeat…: Ododo Re, ko mase sakawe, OLORUN!
Olanla Re ko mase fenuso, afola sola,
Afun ni ma siregun, dansaki Re o Ologo ninu Orun…

Chorus!

Lead : OLORUN mi Jolododo, Jehovah mi Jolododo

Response: OLORUN mi Jolododo Jehovah Jolododo/2*

Lead: Akoni Eleru Jolododo – JESU mi Jolododo.

Resp: OLORUN mi Jolododo Jehovah Jolododo.

Lead 1
OLORUN mi Jolododo si mi
Nigba taye so po tan, O Jolododo si mi
Nigba teniyan yowo support, O je Alanu si mi
O je Olutunu si mi, Baba dide iranlowo o
O duro digbii-digbii, O duro bi Akoni Eleru ooo…
Nigbati mo wo waju o, mo ri JESU loju ise
Nigbati mo wo ehin, O gbe ja mi ja, o soro mi dayo..Ah!!!

Lead: OLORUN mi Jolododo, Jehovah Jolododo

Resp: OLORUN mi Jolododo Jehovah Jolododo.

Lead: OLURANLOWO mi Jolododo, JESU mi Jolododo

Resp: OLORUN mi Jolododo……

Lead: Atinileyin koju ma ti ni, OLORUN mi Jolododo

Resp: OLORUN mi Jolododo……

Lead 2
O Jolododo, nigbogbo ona Baba mii Jolododo
Oun lo gba Omo Israeli loko eru o
Oun lo gba Heberu meta ninu ina ileeru o
O yo Danieli o, kuro ninu iho kiniuh o

Oun to ba ti so dandan ni ko see, a duro ti ni
OLORUN mi Jolododo, aseda aweda, atori ailaisunwon see
B’Olorun bade o, ta lo le di lowo ise…
B’Olorun ba gbe ranwo died
Baba ta lo le bi leere, asoro se ni
Asoro ma ta se…. Ah!

Call: OLORUN mi Jolododo Jehovah mi Jolododo

Resp: OLORUN mi Jolododo…

Call: O gbe ni ni ja Jolododo o JESU mi Jolododo…

Resp: OLORUN mi Jolododo…..

Call: Nigbati reti pin O Jolododo, JESU mi Jolododo.

Resp: OLORUN mi Jolododo…

Call: Nigba teniyan se bi eniyan, JESU mi duro digbii…

Resp: OLORUN mi Jolododo…..

Call: Akoni Eleru Jolododo o BABA mi Jolododo

Resp: OLORUN mi Jolododo Jehovah Jolododo.

Call: OLORUN mi Jolododo Jehovah Jolododo…

Resp: OLORUN mi Jolododo Jehovah Jolododo.

Connect and follow Busayo Adekunle on:

Credits:
Artist: Busayo Adekunle
Genre: Gospel / Worship
Produced by: Olugbenle Matthew
Directed by: Korrectfilm


Discover more from Gospelbuzz

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

RELATED ARTICLES

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.

- Advertisment -

Most Popular